2 Sámúẹ́lì 16:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Láyé ìgbà yẹn, ńṣe ni wọ́n máa ń wo ìmọ̀ràn tí Áhítófẹ́lì+ bá fúnni bí ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run tòótọ́ sọ.* Irú ojú yẹn náà sì ni Dáfídì àti Ábúsálómù fi máa ń wo gbogbo ìmọ̀ràn Áhítófẹ́lì.
23 Láyé ìgbà yẹn, ńṣe ni wọ́n máa ń wo ìmọ̀ràn tí Áhítófẹ́lì+ bá fúnni bí ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run tòótọ́ sọ.* Irú ojú yẹn náà sì ni Dáfídì àti Ábúsálómù fi máa ń wo gbogbo ìmọ̀ràn Áhítófẹ́lì.