-
Jeremáyà 16:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Nítorí náà, màá jẹ́ kí wọ́n mọ̀,
Lọ́tẹ̀ yìí, màá jẹ́ kí wọ́n mọ agbára àti okun mi,
Wọ́n á sì gbà pé Jèhófà ni orúkọ mi.”
-
21 “Nítorí náà, màá jẹ́ kí wọ́n mọ̀,
Lọ́tẹ̀ yìí, màá jẹ́ kí wọ́n mọ agbára àti okun mi,
Wọ́n á sì gbà pé Jèhófà ni orúkọ mi.”