Sáàmù 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jọ̀wọ́, fòpin sí ìwà ibi àwọn ẹni burúkú. Àmọ́, fìdí olódodo múlẹ̀,+Nítorí pé Ọlọ́run olódodo ni ọ́,+ tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn+ àti inú lọ́hùn-ún.*+
9 Jọ̀wọ́, fòpin sí ìwà ibi àwọn ẹni burúkú. Àmọ́, fìdí olódodo múlẹ̀,+Nítorí pé Ọlọ́run olódodo ni ọ́,+ tó ń ṣàyẹ̀wò ọkàn+ àti inú lọ́hùn-ún.*+