-
Sáàmù 40:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó gbé mi jáde látinú kòtò tó ní ìró omi púpọ̀,
Láti inú ẹrẹ̀.
Ó sì fi ẹsẹ̀ mi lé orí àpáta;
Ó fi ẹsẹ̀ mi múlẹ̀ ṣinṣin.
-
2 Ó gbé mi jáde látinú kòtò tó ní ìró omi púpọ̀,
Láti inú ẹrẹ̀.
Ó sì fi ẹsẹ̀ mi lé orí àpáta;
Ó fi ẹsẹ̀ mi múlẹ̀ ṣinṣin.