Sáàmù 16:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mo gbé Jèhófà síwájú mi nígbà gbogbo.+ Torí pé ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún mi, mìmì kan ò ní mì mí.*+ Òwe 10:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Kò sí ohun tó máa mú kí àwọn olódodo ṣubú,+Àmọ́ àwọn ẹni burúkú ò ní gbé ilẹ̀ ayé mọ́.+