-
Nọ́ńbà 10:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Nígbàkigbà tí wọ́n bá gbé Àpótí náà, Mósè á sọ pé: “Dìde, Jèhófà,+ jẹ́ kí àwọn ọ̀tá rẹ tú ká, kí àwọn tó kórìíra rẹ sì sá kúrò níwájú rẹ.”
-
-
Sáàmù 21:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ọwọ́ rẹ á tẹ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ;
Ọwọ́ ọ̀tún rẹ á tẹ àwọn tó kórìíra rẹ.
-