Sáàmù 14:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà ìbàjẹ́ ni wọ́n ń hù, ìṣesí wọn sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+ 2 Àmọ́ Jèhófà ń bojú wo àwọn ọmọ èèyàn láti ọ̀runLáti rí i bóyá ẹnì kan wà tó ní ìjìnlẹ̀ òye, bóyá ẹnì kan wà tó ń wá Jèhófà.+ Sáàmù 53:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà àìtọ́ wọn burú, ó sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+ Sefanáyà 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní àkókò yẹn, màá fi fìtílà wá inú Jerúsálẹ́mù fínnífínní,Màá sì pe àwọn tó dẹra nù* wá jíhìn, àwọn tó ń sọ nínú ọkàn wọn pé,‘Jèhófà kò ní ṣe rere, kò sì ní ṣe búburú.’+
14 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà ìbàjẹ́ ni wọ́n ń hù, ìṣesí wọn sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+ 2 Àmọ́ Jèhófà ń bojú wo àwọn ọmọ èèyàn láti ọ̀runLáti rí i bóyá ẹnì kan wà tó ní ìjìnlẹ̀ òye, bóyá ẹnì kan wà tó ń wá Jèhófà.+
53 Òmùgọ̀* sọ lọ́kàn rẹ̀ pé: “Kò sí Jèhófà.”+ Ìwà àìtọ́ wọn burú, ó sì jẹ́ ohun ìríra;Kò sí ẹni tó ń ṣe rere.+
12 Ní àkókò yẹn, màá fi fìtílà wá inú Jerúsálẹ́mù fínnífínní,Màá sì pe àwọn tó dẹra nù* wá jíhìn, àwọn tó ń sọ nínú ọkàn wọn pé,‘Jèhófà kò ní ṣe rere, kò sì ní ṣe búburú.’+