-
Sáàmù 5:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àmọ́ gbogbo àwọn tó fi ọ́ ṣe ibi ààbò á máa yọ̀;+
Ìgbà gbogbo ni wọ́n á máa kígbe ayọ̀.
Wàá dáàbò bo ọ̀nà àbáwọlé wọn,
Àwọn tó nífẹ̀ẹ́ orúkọ rẹ yóò sì máa yọ̀ nínú rẹ.
-