Òwe 1:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọmọ mi, tí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bá fẹ́ fa ojú rẹ mọ́ra, má gbà.+ 11 Tí wọ́n bá sọ pé: “Jẹ́ ká lọ. Ká lọ lúgọ láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀. Àá fara pa mọ́, àá sì dúró de àwọn aláìṣẹ̀ tó máa kó sọ́wọ́ wa.
10 Ọmọ mi, tí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bá fẹ́ fa ojú rẹ mọ́ra, má gbà.+ 11 Tí wọ́n bá sọ pé: “Jẹ́ ká lọ. Ká lọ lúgọ láti ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀. Àá fara pa mọ́, àá sì dúró de àwọn aláìṣẹ̀ tó máa kó sọ́wọ́ wa.