Ìfihàn 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mo gbọ́ tí gbogbo ẹ̀dá tó wà ní ọ̀run àti ayé àti lábẹ́ ilẹ̀+ àti lórí òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn, ń sọ pé: “Kí ìbùkún àti ọlá+ àti ògo àti agbára jẹ́ ti Ẹni tó jókòó sórí ìtẹ́ náà+ àti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà+ títí láé àti láéláé.”+
13 Mo gbọ́ tí gbogbo ẹ̀dá tó wà ní ọ̀run àti ayé àti lábẹ́ ilẹ̀+ àti lórí òkun àti gbogbo ohun tó wà nínú wọn, ń sọ pé: “Kí ìbùkún àti ọlá+ àti ògo àti agbára jẹ́ ti Ẹni tó jókòó sórí ìtẹ́ náà+ àti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà+ títí láé àti láéláé.”+