Sáàmù 94:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà tí mo sọ pé: “Ẹsẹ̀ mi ń yọ̀,”Jèhófà, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ló ń gbé mi ró.+