Sáàmù 16:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mo gbé Jèhófà síwájú mi nígbà gbogbo.+ Torí pé ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún mi, mìmì kan ò ní mì mí.*+ Sáàmù 63:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mo* rọ̀ mọ́ ọ;Ọwọ́ ọ̀tún rẹ dì mí mú ṣinṣin.+ Àìsáyà 41:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’
10 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Má ṣàníyàn, torí èmi ni Ọlọ́run rẹ.+ Màá fún ọ lókun, àní, màá ràn ọ́ lọ́wọ́,+Ní tòótọ́, màá fi ọwọ́ ọ̀tún òdodo mi dì ọ́ mú ṣinṣin.’