1 Kíróníkà 16:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ kọrin sí i, ẹ fi orin yìn ín,*+Ẹ máa ronú lórí* gbogbo àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀.+ Sáàmù 143:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo rántí àwọn ọjọ́ àtijọ́;Mo ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ;+Ó ń yá mi lára láti máa ronú lórí* iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.
5 Mo rántí àwọn ọjọ́ àtijọ́;Mo ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ;+Ó ń yá mi lára láti máa ronú lórí* iṣẹ́ ọwọ́ rẹ.