Sáàmù 29:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 A gbọ́ ohùn Jèhófà lórí omi;Ọlọ́run ológo sán ààrá.+ Jèhófà wà lórí omi púpọ̀.+