Jóṣúà 24:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí náà, mo mú kí àwọn èèyàn rẹ̀wẹ̀sì* kí ẹ tó dé ọ̀dọ̀ wọn, ìyẹn sì mú kí wọ́n sá kúrò níwájú yín,+ ìyẹn ọba Ámórì méjèèjì. Kì í ṣe idà yín tàbí ọfà yín ló ṣe èyí.+ Sáàmù 44:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+
12 Torí náà, mo mú kí àwọn èèyàn rẹ̀wẹ̀sì* kí ẹ tó dé ọ̀dọ̀ wọn, ìyẹn sì mú kí wọ́n sá kúrò níwájú yín,+ ìyẹn ọba Ámórì méjèèjì. Kì í ṣe idà yín tàbí ọfà yín ló ṣe èyí.+
2 Ọwọ́ rẹ ni o fi lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde,+O sì mú kí àwọn baba ńlá wa máa gbé níbẹ̀.+ O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+