Sáàmù 85:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mú wa bọ̀ sípò,* Ọlọ́run ìgbàlà wa,Kí o má sì bínú sí wa mọ́.+ Ìdárò 5:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mú wa pa dà sọ́dọ̀ rẹ, Jèhófà, a ó sì tètè pa dà sọ́dọ̀ rẹ.+ Sọ ọjọ́ wa di ọ̀tun bíi ti àtijọ́.+