Àìsáyà 5:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó yá, ẹ jọ̀ọ́, ẹ jẹ́ kí n sọ fún yín,Ohun tí màá ṣe sí ọgbà àjàrà mi: Màá mú ọgbà tó yí i ká kúrò,Màá sì dáná sun ún.+ Màá fọ́ ògiri olókùúta rẹ̀,Wọ́n sì máa tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀.
5 Ó yá, ẹ jọ̀ọ́, ẹ jẹ́ kí n sọ fún yín,Ohun tí màá ṣe sí ọgbà àjàrà mi: Màá mú ọgbà tó yí i ká kúrò,Màá sì dáná sun ún.+ Màá fọ́ ògiri olókùúta rẹ̀,Wọ́n sì máa tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀.