Sáàmù 49:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ bí a tilẹ̀ dá èèyàn lọ́lá, kò lè máa wà nìṣó;+Kò sàn ju àwọn ẹranko tó ń ṣègbé.+