Sáàmù 34:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Aláìní yìí pe Jèhófà, ó sì gbọ́. Ó gbà á nínú gbogbo wàhálà rẹ̀.+ Àìsáyà 66:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ọwọ́ mi ni ó ṣe gbogbo nǹkan yìí,Bí gbogbo wọn sì ṣe wà nìyí,” ni Jèhófà wí.+ “Màá wá wo ẹni yìí,Ẹni tó rẹlẹ̀, tí ìbànújẹ́ sì bá ọkàn rẹ̀, tó ń gbọ̀n rìrì* nítorí ọ̀rọ̀ mi.+
2 “Ọwọ́ mi ni ó ṣe gbogbo nǹkan yìí,Bí gbogbo wọn sì ṣe wà nìyí,” ni Jèhófà wí.+ “Màá wá wo ẹni yìí,Ẹni tó rẹlẹ̀, tí ìbànújẹ́ sì bá ọkàn rẹ̀, tó ń gbọ̀n rìrì* nítorí ọ̀rọ̀ mi.+