Sáàmù 52:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ṣùgbọ́n màá dà bí igi ólífì tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ nínú ilé Ọlọ́run;Ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í yẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé+ títí láé àti láéláé. Sáàmù 147:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Inú Jèhófà ń dùn sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀,+Sí àwọn tó ń dúró de ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀.+ 1 Pétérù 5:6, 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí náà, ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ lábẹ́ ọwọ́ agbára Ọlọ́run, kó lè gbé yín ga ní àkókò tó yẹ,+ 7 ẹ máa kó gbogbo àníyàn* yín lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ torí ó ń bójú tó yín.*+
8 Ṣùgbọ́n màá dà bí igi ólífì tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀ nínú ilé Ọlọ́run;Ìfẹ́ Ọlọ́run tí kì í yẹ̀ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé+ títí láé àti láéláé.
6 Torí náà, ẹ rẹ ara yín sílẹ̀ lábẹ́ ọwọ́ agbára Ọlọ́run, kó lè gbé yín ga ní àkókò tó yẹ,+ 7 ẹ máa kó gbogbo àníyàn* yín lọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ torí ó ń bójú tó yín.*+