2 Sámúẹ́lì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ogun tí ó wà láàárín ilé Sọ́ọ̀lù àti ilé Dáfídì kò tíì parí; bí Dáfídì ṣe túbọ̀ ń mókè+ ni ilé Sọ́ọ̀lù ń lọ sílẹ̀.+ 2 Sámúẹ́lì 7:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Màá wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ,+ màá sì mú* gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ kúrò níwájú rẹ;+ màá jẹ́ kí orúkọ rẹ lókìkí gan-an+ bí orúkọ àwọn ẹni ńlá tó wà láyé.
3 Ogun tí ó wà láàárín ilé Sọ́ọ̀lù àti ilé Dáfídì kò tíì parí; bí Dáfídì ṣe túbọ̀ ń mókè+ ni ilé Sọ́ọ̀lù ń lọ sílẹ̀.+
9 Màá wà pẹ̀lú rẹ níbikíbi tí o bá lọ,+ màá sì mú* gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ kúrò níwájú rẹ;+ màá jẹ́ kí orúkọ rẹ lókìkí gan-an+ bí orúkọ àwọn ẹni ńlá tó wà láyé.