-
Ìsíkíẹ́lì 43:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Òfin tẹ́ńpìlì náà nìyí. Gbogbo agbègbè tó yí orí òkè náà ká jẹ́ mímọ́ jù lọ.+ Wò ó! Òfin tẹ́ńpìlì náà nìyí.