22 Síbẹ̀, kò sí ìkankan nínú àwọn tó fojú rí ògo mi àti àwọn iṣẹ́ àmì+ mi tí mo ṣe ní Íjíbítì àti ní aginjù, tó tún wá ń dán mi wò+ nígbà mẹ́wàá yìí, tí kò sì fetí sí ohùn mi,+ 23 tó máa rí ilẹ̀ tí mo búra pé màá fún àwọn bàbá wọn. Àní, ìkankan nínú àwọn tó ń fojú di mí kò ní rí ilẹ̀ náà.+