Sáàmù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+ Sáàmù 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run mi, ni inú mi dùn sí,*+Òfin rẹ sì wà nínú mi lọ́hùn-ún.+ Sáàmù 112:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 112 Ẹ yin Jáà!*+ א [Áléfì] Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+ב [Bétì] Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+ Mátíù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 “Aláyọ̀ ni àwọn tó ń wá ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run,*+ torí Ìjọba ọ̀run jẹ́ tiwọn. Róòmù 7:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nínú mi lọ́hùn-ún,+ mo nífẹ̀ẹ́ òfin Ọlọ́run gan-an, Jémíìsì 1:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Àmọ́ ẹni tó bá ń fara balẹ̀ wo inú òfin pípé+ tó jẹ́ ti òmìnira, tí kò sì yéé wò ó, kì í ṣe olùgbọ́ tó ń gbàgbé, àmọ́ ó ti di olùṣe iṣẹ́ náà; ohun tó ń ṣe á sì máa múnú rẹ̀ dùn.+
7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+
112 Ẹ yin Jáà!*+ א [Áléfì] Aláyọ̀ ni ẹni tó bẹ̀rù Jèhófà,+ב [Bétì] Tó sì fẹ́ràn àwọn àṣẹ rẹ̀ gan-an.+
25 Àmọ́ ẹni tó bá ń fara balẹ̀ wo inú òfin pípé+ tó jẹ́ ti òmìnira, tí kò sì yéé wò ó, kì í ṣe olùgbọ́ tó ń gbàgbé, àmọ́ ó ti di olùṣe iṣẹ́ náà; ohun tó ń ṣe á sì máa múnú rẹ̀ dùn.+