Àìsáyà 37:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Wọ́n sì ti ju àwọn ọlọ́run wọn sínú iná,+ nítorí wọn kì í ṣe ọlọ́run, iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn ni wọ́n,+ wọ́n jẹ́ igi àti òkúta. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi lè pa wọ́n run.
19 Wọ́n sì ti ju àwọn ọlọ́run wọn sínú iná,+ nítorí wọn kì í ṣe ọlọ́run, iṣẹ́ ọwọ́ èèyàn ni wọ́n,+ wọ́n jẹ́ igi àti òkúta. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi lè pa wọ́n run.