Sáàmù 23:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 O tẹ́ tábìlì fún mi níwájú àwọn ọ̀tá mi.+ O fi òróró pa orí mi;*+Ife mi kún dáadáa.+