1 Sámúẹ́lì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kò sí ẹni tí ó mọ́ bíi Jèhófà,Kò sí ẹlòmíràn, àfi ìwọ,+Kò sì sí àpáta tí ó dà bí Ọlọ́run wa.+ Àìsáyà 6:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.”
3 Ọ̀kan sì ń sọ fún èkejì pé: “Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+ Ògo rẹ̀ kún gbogbo ayé.”