Sáàmù 90:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 O gbá wọn lọ;+ wọ́n dà bí oorun lásán;Ní àárọ̀, wọ́n dà bíi koríko tó yọ.+ 6 Ní àárọ̀, ó yọ ìtànná, ó sì dọ̀tun,Àmọ́ ní ìrọ̀lẹ́, ó rọ, ó sì gbẹ dà nù.+ 1 Pétérù 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí “gbogbo ẹran ara* dà bíi koríko, gbogbo ògo rẹ̀ sì dà bí ìtànná àwọn ewéko; koríko máa ń gbẹ, òdòdó sì máa ń rẹ̀ dà nù,
5 O gbá wọn lọ;+ wọ́n dà bí oorun lásán;Ní àárọ̀, wọ́n dà bíi koríko tó yọ.+ 6 Ní àárọ̀, ó yọ ìtànná, ó sì dọ̀tun,Àmọ́ ní ìrọ̀lẹ́, ó rọ, ó sì gbẹ dà nù.+
24 Torí “gbogbo ẹran ara* dà bíi koríko, gbogbo ògo rẹ̀ sì dà bí ìtànná àwọn ewéko; koríko máa ń gbẹ, òdòdó sì máa ń rẹ̀ dà nù,