2 Kíróníkà 20:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 ó sì sọ pé: “Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa, ṣebí ìwọ ni Ọlọ́run ní ọ̀run;+ ṣebí ìwọ lò ń ṣàkóso lórí gbogbo ìjọba àwọn orílẹ̀-èdè?+ Ọwọ́ rẹ ni agbára àti okun wà, kò sì sẹ́ni tó lè dojú kọ ọ́.+ Àìsáyà 66:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 66 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé sì ni àpótí ìtìsẹ̀ mi.+ Ilé wo wá ni ẹ lè kọ́ fún mi,+Ibo sì ni ibi ìsinmi mi?”+
6 ó sì sọ pé: “Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa, ṣebí ìwọ ni Ọlọ́run ní ọ̀run;+ ṣebí ìwọ lò ń ṣàkóso lórí gbogbo ìjọba àwọn orílẹ̀-èdè?+ Ọwọ́ rẹ ni agbára àti okun wà, kò sì sẹ́ni tó lè dojú kọ ọ́.+
66 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ọ̀run ni ìtẹ́ mi, ayé sì ni àpótí ìtìsẹ̀ mi.+ Ilé wo wá ni ẹ lè kọ́ fún mi,+Ibo sì ni ibi ìsinmi mi?”+