Émọ́sì 3:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ǹjẹ́ kìnnìún máa ké ramúramù nínú igbó láìjẹ́ pé ó ti rí ẹran tó fẹ́ pa? Ǹjẹ́ ọmọ kìnnìún* máa kùn hùn-ùn láti ibi tó fara pa mọ́ sí láìjẹ́ pé ọwọ́ rẹ̀ ti tẹ nǹkan kan?
4 Ǹjẹ́ kìnnìún máa ké ramúramù nínú igbó láìjẹ́ pé ó ti rí ẹran tó fẹ́ pa? Ǹjẹ́ ọmọ kìnnìún* máa kùn hùn-ùn láti ibi tó fara pa mọ́ sí láìjẹ́ pé ọwọ́ rẹ̀ ti tẹ nǹkan kan?