-
Jẹ́nẹ́sísì 41:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 “Ní báyìí, kí Fáráò wá ọkùnrin kan tó jẹ́ olóye, tó sì jẹ́ ọlọ́gbọ́n, kó fi ṣe olórí ilẹ̀ Íjíbítì.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 41:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Torí náà, Fáráò sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ǹjẹ́ ọkùnrin míì wà tó ní ẹ̀mí Ọlọ́run bí ẹni yìí?”
-