Diutarónómì 32:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí àwọn èèyàn Jèhófà ni ìpín+ rẹ̀;Jékọ́bù ni ogún+ rẹ̀. 10 Ó rí i nínú aginjù,+Ní aṣálẹ̀,+ tó ṣófo, tó ń hu. Ó yí i ká kó lè dáàbò bò ó, ó tọ́jú rẹ̀,+Ó sì ṣọ́ ọ bí ọmọlójú+ rẹ̀. Sekaráyà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, lẹ́yìn tí a ti yìn ín lógo, ó rán mi sí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kó ẹrù yín,+ pé; ‘Ẹni tó bá fọwọ́ kàn yín ń fọwọ́ kan ẹyinjú* mi.+
9 Torí àwọn èèyàn Jèhófà ni ìpín+ rẹ̀;Jékọ́bù ni ogún+ rẹ̀. 10 Ó rí i nínú aginjù,+Ní aṣálẹ̀,+ tó ṣófo, tó ń hu. Ó yí i ká kó lè dáàbò bò ó, ó tọ́jú rẹ̀,+Ó sì ṣọ́ ọ bí ọmọlójú+ rẹ̀.
8 Torí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, lẹ́yìn tí a ti yìn ín lógo, ó rán mi sí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń kó ẹrù yín,+ pé; ‘Ẹni tó bá fọwọ́ kàn yín ń fọwọ́ kan ẹyinjú* mi.+