-
Ẹ́kísódù 32:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ní báyìí, fi mí sílẹ̀, màá fi ìbínú mi tó ń jó bí iná pa wọ́n run, kí o sì jẹ́ kí n sọ ìwọ di orílẹ̀-èdè ńlá dípò wọn.”+
11 Mósè wá bẹ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀,*+ ó sọ pé: “Jèhófà, kí ló dé tí wàá fi bínú gidigidi sí àwọn èèyàn rẹ, lẹ́yìn tí o fi agbára ńlá àti ọwọ́ agbára mú wọn kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì?+
-
-
Diutarónómì 9:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Dá mi dá wọn, màá pa wọ́n run, màá sì pa orúkọ wọn rẹ́ lábẹ́ ọ̀run, sì jẹ́ kí n sọ ìwọ di orílẹ̀-èdè tó lágbára tó sì pọ̀ jù wọ́n lọ.’+
-