Nọ́ńbà 14:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ìgbà wo ni àwọn èèyàn yìí máa jáwọ́ nínú fífojú di mí?+ Ìgbà wo sì ni wọ́n máa tó nígbàgbọ́ nínú mi pẹ̀lú gbogbo iṣẹ́ àmì tí mo ṣe láàárín wọn?+
11 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Ìgbà wo ni àwọn èèyàn yìí máa jáwọ́ nínú fífojú di mí?+ Ìgbà wo sì ni wọ́n máa tó nígbàgbọ́ nínú mi pẹ̀lú gbogbo iṣẹ́ àmì tí mo ṣe láàárín wọn?+