2 Kíróníkà 9:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn ọkọ̀ òkun ọba máa ń lọ sí Táṣíṣì+ pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ Hírámù.+ Ẹ̀ẹ̀kan lọ́dún mẹ́ta ni àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì máa ń kó wúrà àti fàdákà, eyín erin,+ àwọn ìnàkí àti àwọn ẹyẹ ọ̀kín wọlé. Ìsíkíẹ́lì 27:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn ará Gébálì+ tó jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́* tí wọ́n sì já fáfá ló dí àwọn àlàfo ara ọkọ̀ rẹ.+ Gbogbo ọkọ̀ òkun àti àwọn atukọ̀ wọn wá bá ọ dòwò pọ̀.
21 Àwọn ọkọ̀ òkun ọba máa ń lọ sí Táṣíṣì+ pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ Hírámù.+ Ẹ̀ẹ̀kan lọ́dún mẹ́ta ni àwọn ọkọ̀ òkun Táṣíṣì máa ń kó wúrà àti fàdákà, eyín erin,+ àwọn ìnàkí àti àwọn ẹyẹ ọ̀kín wọlé.
9 Àwọn ará Gébálì+ tó jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́* tí wọ́n sì já fáfá ló dí àwọn àlàfo ara ọkọ̀ rẹ.+ Gbogbo ọkọ̀ òkun àti àwọn atukọ̀ wọn wá bá ọ dòwò pọ̀.