Jóòbù 12:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó ń rọ̀jò àbùkù sórí àwọn èèyàn pàtàkì,+Ó sì ń mú kó rẹ àwọn alágbára;* Jóòbù 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó ń gba òye* àwọn olórí àwọn èèyàn,Ó sì ń mú kí wọ́n rìn kiri ní ilẹ̀ tó ti di ahoro, tí kò sì lójú ọ̀nà.+
21 Ó ń rọ̀jò àbùkù sórí àwọn èèyàn pàtàkì,+Ó sì ń mú kó rẹ àwọn alágbára;* Jóòbù 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó ń gba òye* àwọn olórí àwọn èèyàn,Ó sì ń mú kí wọ́n rìn kiri ní ilẹ̀ tó ti di ahoro, tí kò sì lójú ọ̀nà.+
24 Ó ń gba òye* àwọn olórí àwọn èèyàn,Ó sì ń mú kí wọ́n rìn kiri ní ilẹ̀ tó ti di ahoro, tí kò sì lójú ọ̀nà.+