1 Sámúẹ́lì 20:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ṣùgbọ́n Dáfídì fi kún un pé: “Bàbá rẹ mọ̀ dájú pé mo ti rí ojú rere rẹ,+ á sì sọ pé, ‘Ẹ má ṣe jẹ́ kí Jónátánì mọ̀, tó bá mọ̀, inú rẹ̀ á bà jẹ́.’ Àmọ́, bí Jèhófà ti wà láàyè, tí ìwọ náà* sì wà láàyè, ìṣísẹ̀ kan péré ló wà láàárín èmi àti ikú!”+ Sáàmù 116:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn okùn ikú yí mi ká;Isà Òkú dì mí mú.*+ Ìdààmú àti ẹ̀dùn ọkàn bò mí mọ́lẹ̀.+
3 Ṣùgbọ́n Dáfídì fi kún un pé: “Bàbá rẹ mọ̀ dájú pé mo ti rí ojú rere rẹ,+ á sì sọ pé, ‘Ẹ má ṣe jẹ́ kí Jónátánì mọ̀, tó bá mọ̀, inú rẹ̀ á bà jẹ́.’ Àmọ́, bí Jèhófà ti wà láàyè, tí ìwọ náà* sì wà láàyè, ìṣísẹ̀ kan péré ló wà láàárín èmi àti ikú!”+