-
Sáàmù 141:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Má ṣe jẹ́ kí ọkàn mi fà sí ohun búburú kankan,+
Kí n má bàa lọ́wọ́ sí iṣẹ́ ibi pẹ̀lú àwọn aṣebi;
Kí n má ṣe jẹ oúnjẹ aládùn wọn láé.
-