Sáàmù 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Láti ṣe ìfẹ́ rẹ, Ọlọ́run mi, ni inú mi dùn sí,*+Òfin rẹ sì wà nínú mi lọ́hùn-ún.+ Sáàmù 119:97 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 97 Mo mà nífẹ̀ẹ́ òfin rẹ o!+ Àtàárọ̀ ṣúlẹ̀ ni mò ń ronú lé e lórí.*+