Jeremáyà 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Mo rí ọ̀rọ̀ rẹ, mo sì jẹ ẹ́;+Ọ̀rọ̀ rẹ sì di ayọ̀ fún mi àti ìdùnnú ọkàn mi,Nítorí wọ́n ti fi orúkọ rẹ pè mí, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.
16 Mo rí ọ̀rọ̀ rẹ, mo sì jẹ ẹ́;+Ọ̀rọ̀ rẹ sì di ayọ̀ fún mi àti ìdùnnú ọkàn mi,Nítorí wọ́n ti fi orúkọ rẹ pè mí, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.