Jeremáyà 49:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Sí Kídárì+ àti àwọn ìjọba Hásórì, àwọn tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì pa run, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ dìde, ẹ gòkè lọ sí Kídárì,Kí ẹ sì pa àwọn ọmọ Ìlà Oòrùn.
28 Sí Kídárì+ àti àwọn ìjọba Hásórì, àwọn tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì pa run, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ dìde, ẹ gòkè lọ sí Kídárì,Kí ẹ sì pa àwọn ọmọ Ìlà Oòrùn.