2 Sámúẹ́lì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ilé rẹ àti ìjọba rẹ máa fẹsẹ̀ múlẹ̀ títí láé níwájú rẹ; ìtẹ́ rẹ á sì fìdí múlẹ̀ títí láé.”’”+ 1 Àwọn Ọba 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ọba tún fi eyín erin ṣe ìtẹ́ ńlá kan,+ ó sì fi wúrà tí a yọ́ mọ́ bò ó.+ 1 Kíróníkà 29:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Sólómọ́nì jókòó sórí ìtẹ́ Jèhófà+ gẹ́gẹ́ bí ọba ní ipò Dáfídì bàbá rẹ̀, ó ṣàṣeyọrí, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ń ṣègbọràn sí i.
23 Sólómọ́nì jókòó sórí ìtẹ́ Jèhófà+ gẹ́gẹ́ bí ọba ní ipò Dáfídì bàbá rẹ̀, ó ṣàṣeyọrí, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì ń ṣègbọràn sí i.