1 Àwọn Ọba 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìgbà náà ni Sólómọ́nì kọ́ ibi gíga+ kan fún Kémóṣì, ọlọ́run ìríra Móábù, lórí òkè tó wà níwájú Jerúsálẹ́mù, ó sì tún kọ́ òmíràn fún Mólékì,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì.+ Ìṣe 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà sí Jerúsálẹ́mù+ láti òkè tí wọ́n ń pè ní Òkè Ólífì, tó wà nítòsí Jerúsálẹ́mù, ó tó ìrìn ọjọ́ sábáàtì kan.
7 Ìgbà náà ni Sólómọ́nì kọ́ ibi gíga+ kan fún Kémóṣì, ọlọ́run ìríra Móábù, lórí òkè tó wà níwájú Jerúsálẹ́mù, ó sì tún kọ́ òmíràn fún Mólékì,+ ọlọ́run ìríra àwọn ọmọ Ámónì.+
12 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà sí Jerúsálẹ́mù+ láti òkè tí wọ́n ń pè ní Òkè Ólífì, tó wà nítòsí Jerúsálẹ́mù, ó tó ìrìn ọjọ́ sábáàtì kan.