Sáàmù 48:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ 3 Nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò,Ọlọ́run ti jẹ́ kí a mọ̀ pé òun ni ibi ààbò.*+ Sáàmù 78:68 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 Àmọ́, ó yan ẹ̀yà Júdà,+Òkè Síónì, èyí tí ó nífẹ̀ẹ́.+ Hébérù 12:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì
2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ 3 Nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò,Ọlọ́run ti jẹ́ kí a mọ̀ pé òun ni ibi ààbò.*+
22 Àmọ́ ẹ ti sún mọ́ Òkè Síónì+ àti ìlú Ọlọ́run alààyè, Jerúsálẹ́mù ti ọ̀run+ àti ọ̀kẹ́ àìmọye* àwọn áńgẹ́lì