-
Nehemáyà 9:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 “Ní báyìí, ìwọ Ọlọ́run wa, Ọlọ́run títóbi, alágbára ńlá, tó sì yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù, tó ń pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́, tí ó sì ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn,+ má fojú kékeré wo gbogbo ìnira tó bá àwa, àwọn ọba wa, àwọn ìjòyè wa,+ àwọn àlùfáà wa,+ àwọn wòlíì wa,+ àwọn baba ńlá wa àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ láti ìgbà àwọn ọba Ásíríà+ títí di òní yìí.
-