Jóòbù 14:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 O máa pè, màá sì dá ọ lóhùn.+ Ó máa wù ọ́ gan-an láti rí* iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. Sáàmù 71:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Kódà tí mo bá darúgbó, tí mo sì hu ewú, Ọlọ́run, má fi mí sílẹ̀.+ Jẹ́ kí n lè sọ nípa agbára* rẹ fún ìran tó ń bọ̀,Kí n sì sọ nípa agbára ńlá rẹ fún gbogbo àwọn tó ń bọ̀.+
18 Kódà tí mo bá darúgbó, tí mo sì hu ewú, Ọlọ́run, má fi mí sílẹ̀.+ Jẹ́ kí n lè sọ nípa agbára* rẹ fún ìran tó ń bọ̀,Kí n sì sọ nípa agbára ńlá rẹ fún gbogbo àwọn tó ń bọ̀.+