Hébérù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wà láàyè, ó sì ní agbára,+ ó mú ju idà olójú méjì èyíkéyìí lọ,+ ó sì ń gúnni, àní débi pé ó ń pín ọkàn* àti ẹ̀mí* níyà, ó ń pín àwọn oríkèé àti mùdùnmúdùn sọ́tọ̀ọ̀tọ̀, ó sì lè mọ ìrònú àti ohun tí ọkàn ń gbèrò.
12 Torí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run wà láàyè, ó sì ní agbára,+ ó mú ju idà olójú méjì èyíkéyìí lọ,+ ó sì ń gúnni, àní débi pé ó ń pín ọkàn* àti ẹ̀mí* níyà, ó ń pín àwọn oríkèé àti mùdùnmúdùn sọ́tọ̀ọ̀tọ̀, ó sì lè mọ ìrònú àti ohun tí ọkàn ń gbèrò.