Òwe 9:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Má ṣe bá afiniṣẹ̀sín wí, torí á kórìíra rẹ.+ Bá ọlọ́gbọ́n wí, yóò sì nífẹ̀ẹ́ rẹ.+ Òwe 19:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Gbá afiniṣẹ̀sín,+ kí aláìmọ̀kan lè ní àròjinlẹ̀,+Sì bá olóye wí, kí ìmọ̀ rẹ̀ lè pọ̀ sí i.+ Òwe 25:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bíi yẹtí wúrà àti ohun ọ̀ṣọ́ tí wọ́n fi wúrà tó dára ṣeNi ọlọ́gbọ́n tó ń báni wí jẹ́ ní etí ẹni tó ń gbọ́ràn.+
12 Bíi yẹtí wúrà àti ohun ọ̀ṣọ́ tí wọ́n fi wúrà tó dára ṣeNi ọlọ́gbọ́n tó ń báni wí jẹ́ ní etí ẹni tó ń gbọ́ràn.+