-
1 Sámúẹ́lì 10:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Lẹ́yìn náà, wàá dé òkè Ọlọ́run tòótọ́, níbi tí àwùjọ kan lára àwọn ọmọ ogun Filísínì wà. Tí o bá dé inú ìlú náà, wàá pàdé àwùjọ àwọn wòlíì tó ń sọ̀ kalẹ̀ bọ̀ láti ibi gíga, àwọn tó ń lo ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín àti ìlù tanboríìnì àti fèrè àti háàpù wà níwájú wọn, bí wọ́n ti ń sọ àsọtẹ́lẹ̀.
-