Mátíù 26:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ẹ̀dùn ọkàn bá mi* gan-an, àní títí dé ikú. Ẹ dúró síbí, kí ẹ sì máa ṣọ́nà pẹ̀lú mi.”+ Máàkù 14:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ó mú Pétérù, Jémíìsì àti Jòhánù dání pẹ̀lú rẹ̀,+ ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í ní ẹ̀dùn ọkàn gidigidi,* ìdààmú sì bá a gan-an.
38 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ẹ̀dùn ọkàn bá mi* gan-an, àní títí dé ikú. Ẹ dúró síbí, kí ẹ sì máa ṣọ́nà pẹ̀lú mi.”+
33 Ó mú Pétérù, Jémíìsì àti Jòhánù dání pẹ̀lú rẹ̀,+ ó wá bẹ̀rẹ̀ sí í ní ẹ̀dùn ọkàn gidigidi,* ìdààmú sì bá a gan-an.